Pepenazi – The Invisible Ark Lyrics

Pepenazi – The Invisible Ark Lyrics

Download

(Verse)

Olorun ko da bi omo eniyan, eniyan, eniyan, aronipin, t’eda ba dabi Olorun, oh oh nkan be

Won le nipe, k’ojo ma ro, e den wa ba ile aye je, e den fe k’oju ija s’olorun, oh oh, eniyan, aronipin

Olorun be loke, asoro ma ye, tori iwo ko lo da mi, iwo ko lo da mi, ohh eniyan, aronipin

Iwo ko lo da mi, iwo ko la mu mi dahba, iwo ko lo to mi, olorun lo to mi, aronipin, eku iya oh

Adaba, adaba oh, adaba oh oh, sokale wa

Come and heal the world, come and heal the world, e ti so ile aye do sodom and gomora ohh, social media eniyan, aronipin

Eniyan, aronipin, eniyan, aronipin, odun tuntun

Leave a Reply